ISAKOSO IJOBA IPINLE OGUN FOWOSI OPOLOPO ISE IDAGBASOKE ATI AGBEGA IPO AWON OBA.


Laipe julo yi ni igbimo ijoba Ipinle yi labe Gomina wa asoludero Omo oba Dapo Abiodun fowosi akotun opolopo akanse ise idagbasoke ilu yika origin merin Ipinle yi bee sini won tun se agbega sipo awon oba alaye  awon igbese wonyi lo je ipinnu Gomina wa lati le rii wipe igbayegbadun mutumuwa wa ni ibamu pelu  alaafia ilu ti yoo si din sisa ti awon eniyan nsa kuro loko wa si arin ilu.
        Lara akanse ise naa ni Ile adagbe oniyara meji ti o le ni irinwo, mejidinlogbon Ile awon Omo igbimo Asofin, Ile aladagbe alagbole mejidinlogbon ni GRA Ibara Abeokuta pelu atunko Ile awon Gomina ni Asokoro nilu Abuja. 
      Bakanna opolopo atunse oju ona ko gbeyin bii ona Okun owa, ijebu ode, Ago iwoye ijebu Igbo, Abraham Adesanya Polythenic , Odeda olugbo,aAyobo mopol junction, Lannfewa Ota, Agbala ni lperu.
        Lori agbega ipo oba alaye Akoko tilu Tongeji Yewa, Onitafin tilu Tafin Egba, Olu Orile itori odo Egba.
       Ninu atejade eyi ti Oludamoran leka iroyin Gomina fowosi Hon. Kayode Akinmade se alaye wipe Gomina Abiodun se gbogbo awon eto yi yika Yewa, Egba, Ijebu ki gbogbo eniyan le mo wipe won ko fari spa kan dapa kan si, Oludamoran tesiwaju wipe gbogbo awon akanse ise idagbasoke  yi yoo tunbo mu Ipinle yi gasoke pelu okiki re  eyi ti o nfa awon olokowo wolu wa ti o je  idunnu si agbekale eto Gomina wa.

Post a Comment

0 Comments