ALAGA AYAJO OLORUNDA 2026 PE FUN ISOWOPO ATI ISOKAN.


         Alaga ayeye ayajo Olorunda Oloye Mubashir Abdulaziz Ekerin tilu Olorunda  ti kesi gbogbo Omo ati olugbe ilu naa lati wa ni isowopo ATI isokan kilu naa le tunbo maa tesiwaju . Alaga naa eniti o pe ipe yi lojo ifojomito oro pelu awon oniroyin fun ayeye olosekan ti nlo lowo tesiwaju wipe isokan ati isowopo yi ni yoo mu ogo ilu naa buyo soke ti Ile ise ati okowo nlanla file wolu wa.
      Alaga kesi awon odo lati ri Ara won  gegebi atupa imole ojo ola ilu naa . Oloye Ekerin kesi gbogbo eniyan lati gbe wipe ibi ti eniyan ba ngbe ni o maa nse nipa idi eyi ki won mase dagunla si ohunkohun ti yoo ba mu idagbasoke Balu naa.
     Alaga naa kesi awon obi lati komo won leko iwe, ki awon odo paapaa si fonu seko won laiko DARAPO mo egbekegbe tiyoo ba oruko molebi pelu ilu naa je.

Post a Comment

0 Comments