EMI KOYI TI DURO NIPA MIMU IDAGBASOKE BALU OLORUNDA


          Oba Olusegun Joshua Enitan Philip Ogunsola Orunda tilu Olorunda ti bura folorun seri wipe idagbasoke ilu naa sese bere ni, oba naa seleri wipe oun yoo mulu naa dele ileri re. 
        Oba Ogunsola moro yi waye lasiko iforowero pelu Olootu iwe iroyin Alukoro laafin fun ipalemo ayeye odun Olorunda naa.oba naa se alaye wipe gbogbo ohun ti o lo seyin wa gegebi anfani ilu naa ni yoo pada wa wa nitori awon Koni fi ijoba pelu awon toro kan sile lorun.
      Oba Ogunsola wa lo akoko yi lati fi kesi gbogbo Omo ilu naa ti won wa nipo ise ijoba lati jowo boju weyin,.ki won gbelu naa sipo ti o ba ye,bakanna awon to wa Nile ati oloselu paapaa sowopo pelu ife, isokan ati agboye Ara eni ki won dira won losusu Owo.
      Lakotan oba naa ro gbogbo awon obi lati fomo won leti mora, ki won dekun iwakiwa.

Post a Comment

0 Comments