FPI ILARO YOO DARAPO MOLE ISE OLOkOWO LAIPE.... AKINDE

    Ile eko nla Gbogbonise ti ayipada ti ba oruko re si Yunifasiti Gbogbonise tilu Ilaro ti ni erongba lati DARAPO mo Ile ise olokowo nigbati won yoo so gbogbo ise Owo won Nile eko naa di eyi won bere sini pese re sita fun lilo mutumuwa pelu fifi ranse si oke okun.


    Adele oga agba Ile eko naa Dokita M. A Akinde lo eyi di mimo lasiko iforojomitoro pelu awon oniroyin logba Ile eko naa nilu Ilaro labe akori ayeye konfokesan eleketalelogun Ile eko naa. Oga agba naa se alaye wipe opolopo ise olokankojokan ni o ti wa nile agbende Ile ise okowo tile eko naa yoo maa pese re fun sita fun lilo ara ilu lowo pooku . Lara ohun ti won se afihan re ni ero ti o le sepo pupa .ero ti o le yin agbado, opolopo ohun Ile , eelo asaraloge lorisirisi, ipese ire oko bii tomato, efon, at ni ero ti wa lori re lati maa pese re labele ati ifiranse si oke okun. Oga agba naa wa rawo ebe si enikeni ti won ba Fe se iranlowo  funle eko naa lati wa fun ijiroro pelu asoyepo.

Post a Comment

0 Comments