YIYAN AWUJALE TUNTUN, GOMINA ABIODUN SOKO ORO SI AWON TI O NTAN IROYIN ELEJE KALE


      GOMINA Ipinle Yi Omo- oba Dapo Abiodun CON TI  awon iroyin  eleje adaluru ti  o ntan kale lori yiyan Awujale tuntun gegebi iro patapata wipe oun ati awon afobaje ti pamopo lori yiyan Awujale tuntun naa. Gomina so wipe ko si otito kankan nibe.
        Gomina je ko di mimo wipe lotito ni ipade waye laarin oun ati awon afobaje sugbon ki alaafia pelu ifokanbale le wa nipa igbese  ti yoo mu eto naa lo geerege ni laiko si ikunsinu tabi awuyewuye kan ti yoo da alaafiaà ilu ru ni, bakanna ninu ipade yi ni asoyepo wa wipe enikeni ti o ba kowe ehonu kan sita lo gba pada fun itesiwaju idagbasoke otun lori yiyan Omo- oye naa ati ibowo fun eto ise ati isedale Ile Ijebu lapapo.
         Ninu atejade eyi ti Oloye Kayode Akinmade Oludamoran loro Iroyin fun Gomina fowosi tesiwaju wipe kosi igba kankan ti Gomina Abiodun kowe tabi soro idukoko mo enikeni tabi awujo kankan lori yiyan Omo- oye fun ipo Awujale,.patapata julo oro nla kabiti  
wipe"kosi Kuye,kosi Awujale" won wa sapejuwe gbolohun yi gegebi iparomoni ti o jina ba otito.
       Gomina Abiodun wa je ko di mimo fun gbogbo eniyan wipe oun bowo fun isese ati isedale eto oye jije , oun si duro lati rii wipe yiyan Omo- oye fun ipo Awujale lo nirowo irose laiko mu alaafia dida alaafia ilu ru waye.
         Nibayi oro amoran kan ti wa lo sodo enikeni, igbimo kan pelu awon oniroyin lati maa kan sibi ti o ba ye fun ohunkohun lori yiyan Omo- oye fun ipo Awujale tile Ijebu.

Post a Comment

0 Comments