IPINLE OGUN YOO FOWOSI MILIONU MEWA OWO DOLLAR FUN OKOWO EPO PUPA


Ni bii ose meji si asiko yi ni Ijoba Ipinle yi labe Gomina wa Omo oba Dapo Abiodun  pelu ile kan ni Orile Moroccan yoo jijopawopo fowosi owo tabuwa kan ti o milionu mewa owo Dollar fun ipese ati okowo epo pupa ni Ipinle yi 
Gomina Abiodun  lo  so eyi  di mimo lasiko ti o gba alejo Oga agba ile ise olokowo NigerianIvestiment Promotion Commission Aisha Rimi pelu Oludari  ile ise International Expansion of Jose Batista SobinhoFabio Maia pelu elegbe won lati eka olohun osin abiye ni Oke mosan laipe yi.
Gomina tesiwaju wipe bi ifowosi adehun owo ba pari ,Ipinle Ogun wa yi you okan pataki ninu ipese epo pupa bee sini yoo oro aje lo soke, anfani si wa lati maa fi ranse si oke okun eyi yoo si mu ki Ipinle paapaa  wa niwaju pelu iduro sinsin niun eka oro aje  okowo lagbaye.

Post a Comment

0 Comments