AYAJO OLORUNDA, OBA OGUNSOLA GESHIN YIKA ILU PELU SISI PAPA ERE IDARAYA IGBALODE


       Gbogbo Omo ilu Olorunda lokunrin, lobinrin , lomode lagba ni ijoba ibile Ariwa Abeokuta lo tuyeye tuyaya darapo mo Oba  Olusegun Joshua Enitan Philip Ogunsola Orunda tilu Olorunda bere ayeye ayajo Olurunda olosekan eyi ti o bere lojo kerinlelogun osu kejo odun yi.
       Oba Ogunsola dupe lowo gbogbo eniyan fun atileyin lati asiko igbopa ase ati igbade, ki won tunbo tesiwaju ki ohun meremere  le wolu Olorunda wa.
       Ni papa isere igbalode ti kabiyesi se agbekale re won sapejuwe re gegebi idagbasoke ti o dara pupo larin ilu tabi agbegbe kan ,opolopo awon Omo ti o ba ni ebun yoo loo.
       Oba Ogunsola wa kesi awon obi pelu alagbato lati yonda awon Omo won ma sere idaraya kan si ekeji nitori o ti lowo lori lode oni yii.

Post a Comment

0 Comments