WUTUBA META LO GBE ILEYA ODUN YI DURO.......Imam Ojetola. Alhaji Lukman Ojetola Ijo Ansar-ud-deen lmasayi time sapejuwe odun Ileya gegebi eleka wutuba meta . Imam naa se alaye wipe wutuba meta ni o gbe ileya odun Yi duro, ekinni ni wutuba ojo jimoh, elekeji ni wutuba ti won ka lojo satide arafa, eleketa ni wutuba irun ileya lojo isimi. Imam naa tesiwaju wipe orire Pataki ni o je fun musulumi nipa idi eyi ki gbogbo musulumi ri ara won gegebi olorire ninu odun ileya Yi, sugbon ki won mu eko pataki to odun Ileya ko wa lo bakannaa ni ki won maa sika ileri ati adeun won se loorekoore.lmam waro gbogbo awon Alfa ti won maa nse waasi lati maa no iberu olorun lookan Aya won.lmam Ojetola kesi ijoba lpinle lati gba oluko Mualem pada si awon ile eko alakobere was gegebi o ti se wa ni aye atijo opolopo awon omo musulumi nimo Alquran ti won di tun kawe daradara.
ODO MUSULUMI, E MAA TELE ASIWAJU YIN.... Imam Adegoke. Oluko nipa eko Alquran kan ti gba awon odo musulumi lamoran lati maa tele awon asiwaju won,ki won maa wo awokose won daradara ohun rere tiru agba been ngbese lawujo yato kiru awon odo maa se ife inu won tickets o tako ilana esin ti won gbe Kari. Alhaji Lateef Adegoke Imam Ijo Allahu Lateef Imasayi ati oludasile ile eko Allahu Lateef lo gba won lamoran Yi lojo odun Ileya tesiwaju wipe opolopo odo musulumi ni won ya kuro loju ti won lowo asiwaju won, eyi ko si mu aponle ba won lawujo. Imam wa ryo won lati yago fun iwakiwa pelu lilo etanu si awon asiwaju won. Imam Adegoke Soo di mimo wipe opolopo ohun meremere ni o to wa lode oni yi, ki awon roun lati se idasile re to yoo si so won di olokiki lawujo.lmam wa ki gbogbo musulumi lagbaye ku ewu odun Ileya.